Oriki Orí
Orì lo ri da eni esi oridaye Orisa lo npa ni i da on pa Orisani i da bi ishu on sun aiye ma pa te mi da Orì mi ma se Orì he he ki o ma gba bode.
Orì Nikon lo to alasan ba rokun bi mo ba lowo lowo Orì ni n o ro fun ire gbogbo ti mo ba ni laye Orì ni n o ro fun Orí mi, iwo ni.
Orí san mi. Orí san mi. Orí san igede. Orí san igede.
Orì otan san mi ki nni owo lowo. Orì tan san mi ki nbimo le mio.
Orì oto san mi ki nni aya. Orì oto san mi ki nkole mole.
Orí san mi o. Orí san mi o. Orí san mi o. Oloma ajiki, iwá ni mope.
Bí o bá maa lówó, Bééré lówó orí re. Bí o bá máa sòwò, Bééré lówó orí re w o.
Bí o bá máa kolé o, Bééré lówó orí re. Bí o bá máa láya o, Bééré lówó orí re wo.
Orí máse pekún dé. Lódò re ni mi mbò. Wá sayéè mi di rere.
Orí mi yé o, jà jà fun mi. Èdá mi yé o, jà jà fun mi. Ase.
Òtún awo Ègbá Òsì awo Ìbarà bí a kò bàfi òtún kí a fi òs ì we òsi ara kì ì mó
Dífá fún Awun tó nio rè é we orí olà l`òdò Àwé l`ówó, àwè ní ire gbogbo.
Orí pèlé, Atèté níran Atèté gbe ni kóòsà. Kò sóòsà tíí dá `níí gbè lèyín orí eni.
Orí pèlé, Orí àbíyè, eni orí bá gbeboo ré, kó yo sèsè.
Ya ki nya, ya ki nya, ya ki nya lóro.
Òdàrà Ya we `se, ya we `se l`óro.
Ódàrà ya we `se, ya we `se l`oro.
Ódàrà ya we `se, ya we `se l`oro.
Comentarios