Entradas

Mostrando entradas de diciembre 8, 2014
Òsá Ìwòrì A Ifá pé kí eléyìun ó rúbo. Ayé ó ye é, nnkan è ò níí bàjé. Ìségun ni kí eléyìun ó rúbo sí, yóó ségun, ire è ó sì pò. Òsá pàá pàá Ìwòrì wààràwà A díá fún Olókòso Làlú Bámbí omo arígba ota ségun Àwon Elénìní tó pò yìí Òun le ségun gbogbo won báyìí? Wón ní kí Sàngó ó rúbo Wón ní láko láko ní ó rúbo Sàngó bá  rú òpòlopò owó  Ó rúbo tán Ní ón bá gbógun ti Sàngó Ni Sàngó bá ké Ó ni ‘Òsá pàáááá’ Gbogbo wón bá n gbòn Yóó bàá tún wí ‘Ìwòrì wàràràràrà’ Àwon Awo è méjèèjì ni n kí ní òfurufú Pé ebo tí ón rú fún òun Lòún fi n dá bírà báyìí Ifá pé kí eléyìun ó rúbo è kó pé Pé òún ó ba ségun Sàngó bá ségun tan Ní wá n jó ní n yò Ní n yin àwon Babaláwo è Àwon Babaláwo n yin Ifá Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí Òsá pàá pàá Ìwòrì wààràwà A díá fún Olúkòso Làlú Bámbí omo arígba ota ségun Nígbà tí n be láàrin òsììrì Tí n be láàrin Òtá sángílítí Ebo n wón ní ó rú Ó gbébo nbè Ó´rúbo Mo mòmò sebo Òsá pàá o Mo sì sebo Ìwòr
Imagen
Òsá Ìwòrì A Ifá pé kí eléyìun ó rúbo. Ayé ó ye é, nnkan è ò níí bàjé. Ìségun ni kí eléyìun ó rúbo sí, yóó ségun, ire è ó sì pò. Òsá pàá pàá Ìwòrì wààràwà A díá fún Olókòso Làlú Bámbí omo arígba ota ségun Àwon Elénìní tó pò yìí Òun le ségun gbogbo won báyìí? Wón ní kí Sàngó ó rúbo Wón ní láko láko ní ó rúbo Sàngó bá  rú òpòlopò owó Ó rúbo tán Ní ón bá gbógun ti Sàngó Ni Sàngó bá ké Ó ni ‘Òsá pàáááá’ Gbogbo wón bá n gbòn Yóó bàá tún wí ‘Ìwòrì wàràràràrà’ Àwon Awo è méjèèjì ni n kí ní òfurufú Pé ebo tí ón rú fún òun Lòún fi n dá bírà báyìí Ifá pé kí eléyìun ó rúbo è kó pé Pé òún ó ba ségun Sàngó bá ségun tan Ní wá n jó ní n yò Ní n yin àwon Babaláwo è Àwon Babaláwo n yin Ifá Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí Òsá pàá pàá Ìwòrì wààràwà A díá fún Olúkòso Làlú Bámbí omo arígba ota ségun Nígbà tí n be láàrin òsììrì Tí n be láàrin Òtá sángílítí Ebo n wón ní ó rú Ó gbébo nbè Ó´rúbo Mo mòmò sebo Òsá pàá o Mo sì sebo Ìwòrì wààràwà Mo mòmò ségun Béè
Imagen
Òsá Òyèkú A Ire fún eléyìun, ayé ó ye é. Ifá pé kó rú òpòlopò èkuru funfun lébo. Kó tún fí èkuru náà bòkè ìpòrí è.  Ire ajé fún un. Nnkan tí sì n bà á nínú jé ó dayò láìpé. Níbi táa gbé moni Níbè làá gbé kí ni Mò gbà N làá kárá Ìregbà Ajèkuru jèwà ló morúko tí èwàá jé A díá fún Adégoróyè Omo Èrùgùn Oyè Níjó tí ón ní ó sá káalè Ebo ní ó se Ayé òun dáa báyìí? Inú òún dùn báyìí? Wón ní ayò lòròò ré ó jàá sí Wón ní òpòlopò èkuru funfun lebo è Kí wón ó wáá gbá ìyè Ifá sí i Kí wón ó fi bo òkè ìpòrí è Wón ní ayé ó ye é Okàan rè ó balè Nnkan è ò níí bàjé Adégoróyè omo Èrùgùn Oyè bá rúbo Ayé bá ye Adégoróyè Ó gorí oyée Baba è Ó n lówó N lájé Ó ní háà Bì ò bá a sí àwon Ajèkurujèwà Òun a lè mo nnkan tí Òsayèkú ú je Tíí fíí gbeni? Ó níbi táa bá gbé moni Nìbé làá gbé kí ni Mò gbà N làá kí ará Ìregbà Ajèkuru jèwà ló morúko tí èwàá jé A díá fún Adégoróyè Omo Èrùgùn Oyè Èyí tí ón ní ó sá káalè Ebo ní ó se Wón nó gbogbo nnkan è ní ó dáa Adégoróyè omo èrùg
Imagen
Òsá Ogbè A Ifá ve muchas fortunas buenas para esta persona. Sus cosas no se pondrían estropear (Echar a perder). Ifá le desea en el extranjero fortunas. Ellos estarían disputando para esta buena fortuna; Es esta persona que tomaría la primacía (delantera, ventaja). Él se exhorta no estar atento a de la suerte enferma de sus contemporáneos durante su momento de éxito.     Apatapiti   Apitimòpata   La adivinación lanzada para incontable numero de tambores   Ellos estaban acompañando al rey a la ciudad de Ìlájé   Ellos fueron aconsejados a realizar sacrificio   Nosotros ya hemos perfeccionado nuestros vicios ante el rey, todo en coro   ¿' Por qué nosotros debemos estar perdiendo tiempo en sacrificios '?   Apatapiti   Apitimòpata   Adivinación lanzada para el Sèkèrè   Él estaba acompañando al rey a la ciudad de Ìlájé   Le pidieron que realizara sacrificio   Ellos le dijeron que ofreciera dinero suficiente   Y que él estaría allí tan afortunado