Babá Odi Osé
Babá Odi-Ose Idin sé o Ìrèlè sé o Igi ogbà sé Kéni ó lòmíìn Oko kú Kí n lóko Àlè kú Kí n yàn òmíìn Béni Orí ení ò bá kú Eni ilèélè ò le deni Orí ení A díá fún Àjàgùnmòlè Èyí tíí solóríi gbogbo Awo lálàde Òrun Wón ní ó rúbo Wón ní ti n bo òkè ìpòrí è Wón ní ò si nnkankan tó kù mó Ó se é Ayé ye é Èmí è gùn N ní wá n jó ní wá n yò Ní n yin àwon Babaláwo Àwon Babaláwo n yin Ifá Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí Ìdin sé o Ìrèlè sé Igi ogbà sé Kéni ó lòmíìn Oko kú Kí n lóko Àlè kú Kí n yàn míìn Béni Orí ení ò bá kú Eni ilèélè ò leè deni Orí ení A díá fun Àjàgùnmòlè Èyí tíí solóríi gbogbo Awo lálàde Òrun Bí n bá rówó ní Ó dorùn re Ìwo Àjàgùnmòlè Ó dorùn re Bí n bá ráya ní Ó dorùn re Ìwo Àjàgùnmòlè Ó dorùn re Bí n bá rómo bí Ó dorùn re Ìwo Àjàgùnmòlè Ó dorùn re Bí n bá rílé kó Ó dorùn re Ìwo Àjàgùnmòlè Ó dorùn re Bí mo bá e kú Ó dorùn re Ìwo Àjàgùnmòlè Ó dorùn re Poemario de Ifá ocupa el septuagésimo quinto lugar en el orden invariable de los Oddu de Orùnmilá, es un oddu que nos habla l...