IRETE OLOTA
IRETE OWORIN
Como Orunmila conocio el secreto de las Iyaami
Ki'wo se apo duru si mi.
Ki emi se apo duru sio.
Iwo ni, emi ni.
Owuyewuye awo ile Orunmila.
A d'ifa fun Orunmila ti ns' awo lo ilu eleiye.
Orunmila ni ilu eleiye t' on lo yii, on le r'idi nwon?
On si le ko re bo nibe?
Nwon ni k'Orunmila o rubo.
Nwon ni k'Orunmila o to lo r'idi bi ekeiye naa nse s'aiye,
nwon ni k'Orunmila o lo toju apo aso funfun.
Nwon ni k'o ru ori oka.
Nwon ni k'o ru eiyele funfun.
Nwon ni k'o ru obi ifin merin.
Nwon ni k'o ru obi ipa merin.
Nwon ni k' o ru epo.
Nwon ni k'o ru efun.
Nwon ni k' o ru osun.
Nwon ni k'o ru igba kan.
Nwon ni k'Orunmila o lo toju gbogbo nkan yii.
Nigbati Orunmila si toju e tan,
nwon wa gbe apo aso yii,
nwon gbe e ko.
Orunmila ni ha!
Orunmila nlo s'ode Ota.
Nigbati Orunmila de aarin oja, bi
Orunmila ti de, nwon ni haa!
Nwon ni obe de! Eni ti awon o pa je de.
Ni gbobo nwon bere si wi.
Esu l'o nse meji meji, l'onse meta meta.
Esu ti ta parada, o si ti di enia. L'o ba lo kesi
gbogbo awon aje t'o wa l'ode Ota.
O ni haa! O l'Orunmila.
O ni eiye t'Orunmila ni,
O l'o ma ju gbogbo ti'yin lo.
O ni e ko gbogbo eiye ti'yin poo,
e maa ko lo odo e, k'o maa lo ree gba agbara l'odo Orunmila.
Nwon ni ase okunrin naa tun l'eiye?
Esu ni eiye t'Orunmila ni.
O l'oju ti gbogbo nwon lo l'ode Ota.
Esu ni eiye t'Orunmila ni.
Gbogbo nwon bere si da eiye nwon jo.
Nwon ba bere si gbe t'Orunmila lo.
Orunmila ba si gba gbogbo eiye yii lowo nwon poo,
Nigbati'Orunmila wa gba a lowo nwon tan,
l'Orunmila ba nl ojokoo.
Jijokoo t'o jokko,
nwon ba l'awon o ni pa' ju odi da l'ara Orunmila nwon l'awon a maa ba a ja ni.
Nwon l'awon o si binu si i nitori pe o t'asiri awon.
Nwon ni o si fe f' idi awon ni.
Nwon l'afi b'awon ba mu Orunmila t'awon ba pa a.
O wa lo ree pe awon Babalawo.
Orunmila l'o wa ka.
O ri Temaye. B'awo'le o ba gbo' fa, elo ree kesi t'ode.
A d'ifa fun Orunmila n'ijo t'awon eleiye l'awon o pa a.
Nwon n'iwo Orunmila,
iwo l'awon eleiye o pa o,
awon eleiye fe pa o.
Nwon ni o ba ree rubo.
Nwon ni k'Orunmila o toju ekuj ebu n'ijo naa.
Nwon ni k'o si ni adie opipi.
Nwon ni k'o ni eko kan.
Nwon ni k'Orunmila o ni egbefa owo.
Orunmila sise e bee.
Nigbat'ose tan, nwon ba lo fi gbogbo kini yii,
nwon ba fi se Ifa fun Orunmila, nwon ba fi pese.
Nigbati nwon fi pese tan, ti nwon nje e,
nwon ba tun l'awon o mu Orunmila,
nwon wa ti so Orunmila ti ti ti,
nwon o ri Orunmila mu mo.
Nigbati awon o ri i mu mo.
Nwon ni Orunmila,
nwon l'awon o ti se ri o mu?
O ni aje kii roro ko je ekujebu, e ma le pa mi rara.
O ni adie opipi ki r'apa gun ori'le,
nwon o ni le pa on.
Eyii ni ohun t' Orunmila se nijo naa,
eyii ni ohun t'Orunmila se nijo naa,
ti nwon o fi le pa a, nigbati
Orunmila lo s' ode Ota to lo ree r'idi nwon
ESPAÑOL.
Usted me muestra el contenido de un bolso grande,
Yo le muestro el contenido de un bolso grande,
usted tiene,
yo tengo,
Owuyewuye el Babalawo de la casa de Orunmila
(el nombre del adivino sugiere que la situacion aquí es de una confianza y compartimiento mutuo)
Ifa echado para Orunmila en el día que él iba a la tierra de los pájaros.
Orunmila dijo voy a la tierra de los pájaros a aprender su secreto.
¿Mi viaje será acertado?
A Orunmila le fue indicado que hiciera ebo.
El Babalawo dijo que prepara un bolso
hecho de paño blanco,
que debia ofrecer al dueño de una serpiente,
una nuez de kola blanca, cuatro palomas blancas,
cuatro nueces rojas de kola, efun, aceite de palma y de osun
y colocar el ebo en un bolso blanco
y colgar el bolso del techo de su hogar.
(Ebo para la protección contra el uso negativo de la energía elemental.)
Orunmila viajó a Ota y llegó al mercado.
Los pájaros decidieron alimentar a Orunmila
Con una sopa con veneno.
Esu se transformó en una persona
y llamó los amos del pájaro.
Esu les dijo que Orunmila tenia un pájaro que era más poderoso que el suyo.
Esu les dijo que recolectaran sus pájaros
y se lo llevaran a Orunmila.
Trajeron sus pájaros a Orunmila.
Cuando los pájaros estaban recolectados
Orunmila se sento entre ellos.
El pájaro domina dijeron ellos
Tambien dijeron que no le quitarían la vista de encima.
Dijeron que lucharían.
Dijeron que estaban enojados
porque él sabía su secreto.
Dijeron que solo ellos debian saber su secreto
y por eso deseaban matarle.
Ifa consulto a Orunmila
en el día que los pájaros fueron mandados para matarle.
Ifa dijo que hiciera ebo.
Ifa dijo que tomara la semilla ekujebu,
un pollo del opipi,
y seis dineros doblado todo en una hoja.
(Ebo para la protección después de que se haya iniciado un ataque)
Orunmila sobrevivió al ataque.
El pájaro domina dijeron ellos
lo miraban de cerca.
Desearon saber
Orunmila se defendió.
Orunmila dijo que no es difícil
porque usted no puede comer la semilla de ekujebu
y el pollo del opipi tiene alas para volar.
Éstas eran las cosas que protegieron Orunmila contra ataque

Comentarios